Tumgik
naijavoicemedia · 2 years
Text
Music: WIZZY BLIZZY - MY OWN GRIND
Music: WIZZY BLIZZY – MY OWN GRIND
This is another hit song from Wizzyblizzy after dropping a hit song with Lyta MonaLisa crooner , titled : Eleko , Now he his back with another sweet melody to your hears you should all get your speakers fixed ,New single titled : My Own Grind. Promoted by NAIJAVOICE MEDIA
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Wọn maa too tu Sunday Igboho silẹ lahaamọ-Ọlajẹngbesi – Alaroye
Wọn maa too tu Sunday Igboho silẹ lahaamọ-Ọlajẹngbesi – Alaroye
Faith Adebọla Pẹlu ọrọ ti Ọgbẹni Pẹlumi Ọlajẹngbesi, ilu-mọ-ọn-ka lọọya to n ṣoju fun gbajugbaja ajijangbara ilẹ Yoruba nni, Oloye Sunday Adeyẹmọ tawọn eeyan mọ si Sunday Igboho, sọ lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ karun-un, oṣu keji yii, ireti to daju wa pe Sunday Igboho yoo kuro lahaamọ ẹwọn orileede Olominira Benin ti wọn ti i mọ, yoo si dẹni ominira laipẹ.Ọlajẹngbesi lo ṣofofo ọrọ naa sori atẹ…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Awọn ọmọ Rẹmọ, laduugbo Ọṣinbajo, ni ko waa dupo aarẹ lọdun to n bọ – Alaroye
Awọn ọmọ Rẹmọ, laduugbo Ọṣinbajo, ni ko waa dupo aarẹ lọdun to n bọ – Alaroye
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn ọmọ ilu Rẹmọ, ti i ṣe ilu abinibi Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo, labẹ ẹgbẹ ti wọn n pe ni ‘PYO for President’ ti ni ki Igbakeji Aarẹ ile wa yii maa bọ waa dupo aarẹ Naijiria lọdun to n bọ, wọn ni gbogbo ara lawọn fi ṣatilẹyin fun un. Ipinnu pe ki Ọṣinbajo waa dije dupo aarẹ yii ko deede waye, nibi ipade kan ti wọn ṣe pẹlu gbogbo awọn ọmọ Rẹmọ lọjọ kẹrin, oṣu keji, ọdun…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Awọn afẹmiṣofo tun ṣọṣẹ, wọn pa ogun eeyan ni Zamfara, mẹtadinlogun ni Katsina, wọn si ji ọpọlọpọ gbe lọ – Alaroye
Awọn afẹmiṣofo tun ṣọṣẹ, wọn pa ogun eeyan ni Zamfara, mẹtadinlogun ni Katsina, wọn si ji ọpọlọpọ gbe lọ – Alaroye
Faith Adebọla Bawọn ologun ati ẹṣọ alaabo ṣe n ge awọn janduku afẹmiṣofo to n fojoojumọ ṣoro bii agbọn lapa Oke-Ọya ilẹ wa lọwọ, lawọn agbebọn yii n bọ oruka, pẹlu bi wọn tun ṣe ṣakọlu lopin ọsẹ yii si ipinlẹ Katsina ati Zamfara, nibi ti wọn ti fiku oro pa eeyan ti ko din ni mẹtadinlogoji, ti wọn si ji eeyan bii aadọta gbe wọgbo lọ. Oru ọjọ Ẹti, Furaidee, mọju Satide ni wọn lawọn apaayan ti wọn…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Nitori gilaasi, obinrin yii gun aburo ọkọ ẹ lọbẹ pa l’Agbado – Alaroye
Nitori gilaasi, obinrin yii gun aburo ọkọ ẹ lọbẹ pa l’Agbado – Alaroye
 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  Ọrọ ti ko to nnkan lo gbe obinrin yii, Cynthia Olukiowu, ẹni ọgbọn ọdun, de ẹka to n gbọ ẹjọ ipaniyan nipinlẹ Ogun bayii. Niṣe lo fi ọbẹ gun ọmọkunrin ẹni ọdun mejidinlogun to jẹ aburo ọkọ ẹ, to si n gbe pẹlu wọn, lọbẹ lọrun lọjọ Satide to kọja yii, ọmọ naa si ṣe bẹẹ dero ọrun. Ojule keji, Opopona Apogidonoyo, Jafa, l’Agbado, nipinlẹ Ogun ni obinrin yii n gbe pẹlu ọkọ…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Abi iru ki waa leleyii, nitori abọ ounjẹ, Yusuf ṣeku pa alabaagbe rẹ n’llọrin  – Alaroye
Abi iru ki waa leleyii, nitori abọ ounjẹ, Yusuf ṣeku pa alabaagbe rẹ n’llọrin – Alaroye
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ to kọja yii, ni akẹkọọ kan nile ẹkọ olukọni agba Kinsey, niluu Ilọrin, ipinlẹ Kwara, Ahmed Yusuf, ṣeku pa alabaagbe rẹ, Farouk Ojo Ahmed, nitori abọ ounjẹ. Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ ni pe agbegbe Fate, niluu Ilọrin, ni awọn mejeeji gbale si ti wọn n gbe, ṣugbọn sadeede ni aawọ bẹ silẹ laarin wọn latari pe wọn o gbọ ara wọn ye mọ lori bi wọn…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Tension as Zamfara assembly moves to impeach deputy gov, Mahadi Aliyu
Tension as Zamfara assembly moves to impeach deputy gov, Mahadi Aliyu
There is tension in Zamfara State as the state House of Assembly has commenced the impeachment process against the deputy governor, Alhaji Mahadi Aliyu. This is contained in a statement issued in Gusau on Friday by the Director-General, Press Affairs and Public Relations to the legislative arm, Malam Mustafa Jafaru-Kaura. According to the statement, the move followed a presentation of impeachment…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Wahala ẹgbẹ APC, awọn TOP ni kileeṣẹ ọlọpaa gbe kọmiṣanna to wa l’Ọṣun kuro – Alaroye
Wahala ẹgbẹ APC, awọn TOP ni kileeṣẹ ọlọpaa gbe kọmiṣanna to wa l’Ọṣun kuro – Alaroye
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn The Osun Progressives (TOP) ti wọn jẹ igun ẹgbẹ oṣelu APC ti Ọgbẹni Arẹgbẹṣọla n ṣatilẹyin fun nipinlẹ Ọṣun ti ke si ọga agba patapata funleeṣẹ ọlọpaa lorileede Naijiria, IG Usman Baba, lati gbe Kọmiṣanna ọlọpaa to wa l’Ọṣun bayii, Ọlawale Ọlọkọde, kuro kiakia. Alaga wọn, Alhaji Rasaq Ṣalinṣile, sọ fun awọn oniroyin lọsan-an ọjọ Ẹti, Furaidee, niluu Oṣogbo, pe…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Ile-ẹjọ ran ayederu lọọya lẹwọn l’Ekiti – Alaroye
Ile-ẹjọ ran ayederu lọọya lẹwọn l’Ekiti – Alaroye
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Mijisireeti kan to wa l’Ado-Ekiti, nipinlẹ Ekiti, ti ran ọkunrin ẹni ọdun mejilelogoji kan, Abayọmi Kayọde lẹwọn ọṣun mẹfa pẹlu iṣẹ aṣekara, lori ẹsun pe o pe ara rẹ ni agbẹjọro. Awọn agbẹjọro ẹkun Ikẹrẹ-Ekiti lo mu ọkunrin naa, ti wọn si fa a le ọlọpaa lọwọ pẹlu ẹsun pe o funra rẹ ṣe agbelẹrọ ontẹ ati siili awọn agbẹjọro niluu naa, lẹyin to parọ pe oun lọ…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
2023: 14 govs, 24 APC state chairmen have endorsed Tinubu
2023: 14 govs, 24 APC state chairmen have endorsed Tinubu
The director-general of the Bola Tinubu Support Group Council, Mr Abdulmumin Jibrin, has claimed that no fewer than 14 Governors and 24 state Chairmen under the platform of the All Progressives Congress, have endorsed the presidential aspiration of the national leader of the party, Mr Bola Ahmed Tinubu. Jibrin, a former member of the House of Representatives, lost his return to the House in 2019…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
EFCC releases embattled Medview MD, VON DG on bail
EFCC releases embattled Medview MD, VON DG on bail
The Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) has released detained managing director of Medview Airline, Muneer Bankole and the director-general of Voice of Nigeria (VON), Osita Okechukwu, on bail. The duo were detained last week by the anti-graft agency on different corruption allegations. While the Medview Airline boss is accused of allegedly diverting 50 per cent of funds paid to him by…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Umekwe elected CISA president, vows to advance Igbo cultural heritage
Umekwe elected CISA president, vows to advance Igbo cultural heritage
The Council of Presidents of the Council of Igbo States in Americas (CISA) has announced the election of Engr. James Ogbuka Umekwe from Abam/Arochukwu Local Government Area, of Abia State, as its new President to pilot the affairs of the United States apex Igbo organization. CISA Byelaws stipulates a two-year rotational presidency among Igbo Speaking states in alphabetical order and now the baton…
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
YCee – Intenationally (Remix) ft. Nanpa Basico Mp3 Download
YCee – Intenationally (Remix) ft. Nanpa Basico Mp3 Download
YCee – Intenationally (Remix) ft. Nanpa Basico MP3 Download. Talented Act and songwriter, YCee resurfaces with a brand new single titled ”Intenationally (Remix)” The song features Nanpa Basico. The new single serves as a follow up to his previously heard Single playlist titled, “Aunty Lovina ft. Patoranking”. RELATED :   [Music] Show Dem Camp ft. Ladipoe – Savage The song “Intenationally…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Emo Grae – Steady Drinking
Emo Grae – Steady Drinking
Emo Grae – Steady Drinking MP3 Download. Talented Act and songwriter, Emo Grae resurfaces with a brand new single titled ”Steady Drinking” . The new single serves as a follow up to his previously heard Single playlist titled, “Gone”. The song “Steady Drinking” is an amazing number which is a must for your playlist. Listen & Download MP3: Emo Grae – Steady Drinking…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Very best Hookup Internet pages In 12 , 2021
Very best Hookup Internet pages In 12 , 2021
On the downside, Feeld calls for an energetic Facebook account to join, which will isn’t top-quality news for the people of you exactly who don’t have this. On the other hand, the reason for that may be primarily based about its strict privacy policy ~ which is convenient for stopping scammers and bots. Finest websites (such as 20 runner-ups) to get you that one particular-night stand you…
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
The billionaire king of private jet business in Nigeria
The billionaire king of private jet business in Nigeria
For Sam Iwuajoku, the billionaire chairman and chief executive officer of Quits Aviation Services Limited, operators and hosts of ExecuJet facility in Nigeria, it has been a story of success after success. According to the Russian ballet dancer, Anna Pavlova, “Success depends in a very large measure upon individual initiative and exertion, and cannot be achieved except by dint of hard work”.…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes
naijavoicemedia · 2 years
Text
Reekado Banks – Ozumba Mbadiwe (Remix) ft. Fireboy DML Mp3 Download
Reekado Banks – Ozumba Mbadiwe (Remix) ft. Fireboy DML Mp3 Download
Reekado Banks – Ozumba Mbadiwe (Remix) ft. Fireboy DML MP3 Download. Talented Act and songwriter, Reekado Banks resurfaces with a brand new single titled ”Ozumba Mbadiwe (Remix)” The song features Fireboy DML. The new single serves as a follow up to his previously heard Extended playlist titled, “Off The Record Vol. 2 (EP)”. RELATED :   [Music] Shark2six – Anita (Prod. By Major Bangz) The song…
Tumblr media
View On WordPress
0 notes